Ogun abiku
OGUN ABIKU 1. Iyẹ adiẹ dudu, ewe abirikolo, eku asin kan, ọga kan, ẹgusi ti wọn ba ṣẹ silẹ ni ilẹ ọja ati ireke ti […]
OGUN ABIKU 1. Iyẹ adiẹ dudu, ewe abirikolo, eku asin kan, ọga kan, ẹgusi ti wọn ba ṣẹ silẹ ni ilẹ ọja ati ireke ti […]
OGUN IRIKURI:Riri ohun buburu tiko dara ni oju orun bi ki a wipe a ri egun, tabi, ki a ja si odo, tabi ki a […]
SISI LILE OBIRIN:On ni a npe ni Teso, ti won ba fi iru ogun yi le obirin, ko ni je ki enia o le ba […]
OKEPE je ogun ti ma dabo bo awa eda, bi a ba ni iroju ati se ogun yi. kosi ohun tio le ran oluware iba […]
OGUN OJU KOKORO: Oju kokoro ko si ohun ti ko le fa, a ma fa ki omo a ma jale, ama mu ki omode o […]
OGUN ERO MAGUN 1. Ifun ako aja ti o ba se dede ikadi eni, ewe bomubomu ao lo, eku eliri, odidi atare kan, odidi eiyele […]
OGUN MADARIKAN 1. Igbin kan, ao mu iyo afi ka ile birikiti, ao mu igbin na ao fi si arin re, nigbati igbin na ba […]
EBE AWON AGBA Olorun ni o le bẹ won o, ise ti won nse. si ara Eda ko kere, nipa ki a ma je ka […]
OGUN ATOSI 1. Egbo asunwon ati ewe re, egbo atori ati ewe re, tangiri, isu aidan, isu erin, ogede agbagba pipon, ata, Alubosa, iyọ, orogbo […]
Copyright © 2024 | WordPress Theme by MH Themes
Click one of our contacts below to chat on WhatsApp