OGUN MADARIKAN

OGUN MADARIKAN

1. Igbin kan, ao mu iyo afi ka ile birikiti, ao mu igbin na ao fi si arin re, nigbati igbin na ba ran tio ba fe fi enu kan iyo, ao fi okuta wo mole, igba ewe kasan ( (200) ao wa jo gbogbo re po mo igbin yi ati odidi atare kan, nigbati a ba jo tan, ao wa fi te gbogbo oju odu ifa merindinlogun (16.)

Ofo re:Asaopa ko ru gi egun, oyiya won eya oko idioro, nijoti akurumona ba fi enu kan iyo ijọ na ni lo ode orun, ao fi so nti aba fe si, ao ma fifo eko mu.

2. Alabahun kan, iku ijebu 9, odidi atare 4, eyin adie 4, a o jo gbogbo re po, ori aparo kan, ao wa te ni Ogbetu omura.

Ofo re: Elaro, ogunde ọmọdẹ, edi emo oje, odede omo awo wẹri, weri mole fun mi, o ba weri mi, apari awo, aja fun mole, eko fifo mu ni o.