OGUN GBANU GBAHA
Ogun gbanu gbaha, Eniti arun yi ba nse, inu re yio wu lati aiya de odo abe, o si le wipe oso ohun ni egbe, […]
Ogun gbanu gbaha, Eniti arun yi ba nse, inu re yio wu lati aiya de odo abe, o si le wipe oso ohun ni egbe, […]
OGUN BI OYUN BA NBU Ogun dada ni ogun na je, bi oyun ba mbu, bi a ba lo ogun yi, ni agbara Olorun, Oyun […]
ASOGBO Ohun ti a pe ni Asogbo ni wipe ki oyun ki o ba jẹ lara obinrin ni osu meta tabi mefa, tabi meje, tabi […]
OGUN OSE IWEBI 1. Ogun yi dara pupo fun eniti oba loyun, titi ti aboyun yio fi bimo ko ni si iyolenu fun obirin naa […]
OGUN ABIKU 1. Iyẹ adiẹ dudu, ewe abirikolo, eku asin kan, ọga kan, ẹgusi ti wọn ba ṣẹ silẹ ni ilẹ ọja ati ireke ti […]
WAPA je arunti omu opolopo enia lode oni, ona pupo ni won ngba ko wapa. Asa Yorùbá gbàgbó wipe a ma ko wapa nibi ounjé […]
TUNTUNYUNYUN je arun tio buru ju fun eni gbogbo, a si ma yara mu gbogbo omo ika ese tia fi nse anfani kuro nibé, ibere […]
SIMUSIMU:Eniti amodi yi ba nse ni ojo to ti pe ni arun simusimu yi ma se, nigbati o ba ya ti arun na ti wo […]
SISI LILE OBIRIN:On ni a npe ni Teso, ti won ba fi iru ogun yi le obirin, ko ni je ki enia o le ba […]
Copyright © 2024 | WordPress Theme by MH Themes
Click one of our contacts below to chat on WhatsApp