OGUN WAPAWAPA je arunti omu opolopo enia lode oni, ona pupo ni won ngba ko wapa. Asa Yorùbá gbàgbó wipe a ma ko wapa nibi ounjé ajojẹ, won asi ma ko nipa siga ajo mu ati wipe igba tio ni wapa ba fi mu omi, bi elomiran, ba fi igba na mu omi. oluwa ré na yio ko wapa, a o wipe bi oni wapa ba tu ito sile, ti ategun ba gbe si enia lenu ni oju ona, eni na yio gbe wapa pelu, nitori eyi ni a ki se ya enu sile bia ba nlo ni oju ona. Isegun oyinbo gbàgbó wipe wárápá Kiise àrùn ti eniyan lè kó tabi ti o ma n ran.

Tobeejubeelo, ohun tia si le lo fun wapa niwonyi

i. Ao ra igun ayekan ao pa, ao ko gbogbo ohun tia ba ba ninu Igun na, opolopo obuotoyo, ogidi emu ti o ko ba ni omi papa, ao ke sinu sago, a ki ko sinu ape, beni aki ko sinu kerengbe, ninu sago ni a ko si o. Ao di ni enu, ni ojo kesan ao si, eni na yio mu tobila kan, bio ba mu yi o lule bi igba wapa yi tun gbe, ni ojo na ni yio po wapa na ko nidi ojo keji rara.

2. Ewe ila funfun ati pupa, eru awola, ewe ejinrin were, ao se ni agbo, nigbati o pọ tan agbo yi ni yio fi we ni jo na o.

3. Eso peregun, lopolopo, ibi ewure, ibi agutan, iso aparo, esi-agbonrin, odidi igun, ao jo gbogbo re po, nigbati a ba jo tan, ao lo obuotoyo, a da si inu adi eyan, oluware yio ma la, a fi epo ati ori si o.