OGUN TI A FI NWO WERE

WERE: je arun tio po ju ni ile awa enia dudu, ahun ti nsi ma fa were ni awon nkan die ti ndaruko wonyi: Mímú tabi lilọ ogun oloro gẹgẹ bí igbo, kokeeni ati ohun buruku miran, were wa nínú eje irandiran àwon ènìyàn míràn a Si máa fà ki won o ya were lojiji, Bi obinrin ba ko oko ti ko ba te oko re lorun, o le so di were, bi awon omo baba meji ba nja si ogun, a ma ri were nibe, ati wipe won elomiran a sa sa dede wipe awon yio dan ogun wo lara awa eda ama ri were nibe.

1. Apola ijimere, odidi atare meje, eresile ewe abo, ki se wipe ki a ra ni oja o, alo re mu ni-idi re ni 6, ao jo awon nkan meteta po, awa dasi meji, awafi kanhun bilala mo apa kan, ekeji ao po po mo ose oyo, omode were na yio ma fi bo oju, pelu se ti a po ogun mo yi, sugbon eyiti a fi kanhun si ni a ma fi fo eko tutu fun.

2. Egbo ira igbo, alubosa elewe, iyere, kanhun bilala, ere, epo, a wa fi su ole fun were na, ole na ko ni yọ o, were na yio ma sun dada.

3. Igbin kan, alabahun kan, odundun, rinrin, ewe worowo, odidi siri ogede were pipon kan ao jo gbogbo re po, ao ma fi fo eko tutu fun were na, a si ma fi ore osepotu dudu na diedie, a ko gbodo na pupo ju o.

4. Bio ba se okunrin apola ako aja, bi o ba si se obirin apola abo aja, egbo opoki, eso isinko tutu ti o ba sese yanu lori iya re, ewe loniyenye lọpọlọpọ awawa oru ti o gba, epo, adi, ori, ti oru nao ni se rara, a wa ko gbogbo re sinu oru na, oru tio ba tobi ni o. Igo adi mefa (6), ori lọpọlọpọ, epo die, korotikoro ati epo isin ni a ki si ni oru o, a wa wa ewe tabi apadi, a wa san ni ibo, ni ojo keje ni ao si, bi o ba se obinrin, sugbon tio ba se okunrin ni ojo kesan ni ato si o, a wa wa igbako igi ti won npe ni ipọn, nia ma fi bu ogun yi si were na ni enu, bi o ba si we, ogun yi na nia ma fi pa lara.

6. Igbin meta, eja abori meta, ewe oniyenye, ekolo lopolopo, ori ati adi, epo, alubosa elewe, ata were pupa, nigbati a ba ko sinu isasun tan, tio ba se were ti ko soro, ao fi, ori awoko kan si, ti o ba se eyiti npa ariwo pupo, ao ju ori ase si, a wa se obe yi, a gbe fun were na yio ma je ni emeta ni ojumo.

7. Ao toju oru ti o dara, apola ijimere tutu, awa ka eso ibepe, nigbati o ba pon, gbogbo ohuntinbe ninu ibepe na ni ao wo leri apola ijimere yi, a wa ewe oniyenye tutu, ao ko le, a wa san ni ibo, awa so ro si oju ina, nigbati o ba di ojo kesan ao si, ao ma ro po, ao si ma bu fun were na je nigbagbo, were na yio ni alafia.

8. Ao ra agbo kan. a mu lo si idi igi ira igbo, oruko ti a pe nigbati a ba de be ni abalarindin rindin, ao pa agbo yi, ao bo fere orun agbo yi mo idi igi na, a wa gbogbo egbo igi ira igbo na ni awa pa, a wa mu oruko kekere kan Io si idi arun jeran, ao pa oruko na, asi tun bo fere re mọ idi a arunjeran na, a Si wa gbogbo gbongbo arunjeran na ni awapa, gbogbo awon eran yi la ko wale o, a wa toju koko tio ba tobi to adi aro, a o mu ori agbo ati oruko yi afi tele, a wa mu. odidi egboro aja kan, ao lu pa awa gbe le ori oruko ati ti agbo, awa ge gbogbo egbo igi wonyi keke, asi la igba orombo were si, ao bu omi siti yio kun, a wa de, bi o ba se obinrin, ni ojo keje ni a to si, bi-o ba si se okunrin ni, ojo kesan nia o si. Ale fun ọpọlọpọ enia ni agbo yi lo, ohun ti a ma fi si ni wipe ki apa aja si, ki a si ma la orombo were si, ki se wipe kia tun se inawo lekeji, bia ba fe fun elomiran lo.

9. Egbo opoki, egbo ira igbo, imi orun, etu ibon, eso isin ti oba la enu lori iya re mokanlelogoji (41), ewe oniyenye, opolopo ogongo ori akitan. ao gun gbogbo re po, ao ma fi sinu eko gbigbona fun were na ni ojojumo.

10. Egbo iraigbo, egbo opoki, ori odide, imi orun, kanhun bilala, ao gun gbogbo re po, ti yio kunna dada, ama bu sinu eko gbigbona fun were na mu ni ojojumo, werewere re yio si din ku.

11. Odidi abon eyin meta kekeke, eru awonka eyo kan, awa to leri ara won ninu ikoko nla kan, a o ra garawa ito malu meji ao tu sori ogun ti a to sinu ikoko, ama fi-we ni larolaro yio si ma mu.

12. Odidi abon eyin kekeke meta, oko tuntun kan, egbo abo, egbo oloraigbo, egbo opoki, ewe oniyenye, egbo olonra igbo yi yio po ni agbo yio. Ito malu garawa meji, oko ati igbako oka nia fi tele agbo na, a wa ko gbogbo ogun yoku le lori, a wa da ito malu yi le lori, a wa de ni ojo kesan bi o ba se okunrin, sugbon bi o ba se obirin ni ojo keje nia o si agbo, ao wa fi we were na, a o si ma bu agbo yi fun nigbagbogbo lati mu.

13. Ao tojueyin ti adie ba sese ye kan, ewe oniyenye, egbo opoki, ewe-agunnamojo, ewe iyeye, egbo yanrin, iyere, bio ba se okunrin, a o fi abe ifari sinu isasun, bi o ba se obinrin, a mu igbako ipon a fi sinu isasun, ao ge idi ipon na kuro o, ibiti a finro obe ni afi sinu isasun o, awalo gbogbo awon ewe ti ada kọ wonyi ati egbo, awa fi se eiye ega je, ki se wipe ki aba were yi je o, were yi nikan ni a ma to obe na fun o.

14. Ororo eyin adie mewa, ewe Oniyenye, a o ra epo igi odeewese, bi o ba se okunrin ao toju mudunmudun ori akuko adie, bio ba si se obintin a o toju mudunmudun ori abo adie, ati ekolo lopolopo, a wa fi se obe kanna fun were na nigbati aba lo gbogbo ewe wonyi po tan, a wa mu isasun obe yi, fi le were yi lowo, a wi fun were na kio lo fo isasun na si inu igbo ti ese re ko ni te lailai.

15. Apola Omoja, a o ko sinu oru, ewe sawerepepe, kafura, egbo wowo,egbo woruku, ao ge keke, a wa to sinu oru, lori ifun aja ti a gbe tele, odundun, rintin, tete asese daiye, a wa pa igbin tutu pepepe, a wa ko sinu oru na, igbin meta nio. A o ma bu fun were na yio ma la, yio sima fi para, a si le ma bu ogun yi fun awon elomiran, lati ma lo, awon to ba nse aganna tabi awon tio ba nla ala buburu.

16. Eran elede, ewe-ajeobale, ewe imoosun, ewe odundun, ewe ankenleti, ewe agemo ogun, epo oto die, ao jo ororo eyin adie meje sinu isasun pelu eran elede yi, ori nia fi se epo iyo, iyere ni ata re, ninu iyara mi ati je obe yi