OGUN TUNTUNYUNYUN

TUNTUNYUNYUN je arun tio buru ju fun eni gbogbo, a si ma yara mu gbogbo omo ika ese tia fi nse anfani kuro nibé, ibere re a ri ti gbogbo ese yio ma yun oluwaré, titi eni na yio fi ho kan eje, nigbati o ba kan eje yi niari wipe tuntunyunyun ni, ki fun eniti o ba mu-ni alafia lati -le rin, ohun tia si le-lo ni awon ogun wonyi.

1. Eso ibepe, ao sun, a wa lo edu re sinu awo kan, a fi adi si, a ma kan si ese na bi o ba ni oju

2. Egbo inabiri,egbo enuopiri, ata pupa, ati kanhun, imi ewure, a wa gun yio kunna dada, awapo po mo ose, a fi re oju ese na tabi owo na a wa fi ekisa kan we.

3. Egbo ewuro ijebu, egbo enu opiri, epo igi sapo, egbo iyere, ao se ni agbo pelu ata pupa, ama fi jo ese na, iba se owo

4. Egbo ewuro ijebu, epo-ponpola, epo odeowese, egbo iyere, ata were pupa,a wa seni agbo, ama fi jo ese na tabi owo na.