OGUN SISI LILE OBIRIN

SISI LILE OBIRIN:On ni a npe ni Teso, ti won ba fi iru ogun yi le obirin, ko ni je ki enia o le ba sun, iru nkan yi nia pe ni sisi lile obinrin o, bi a ba loogun yi, were ni yi o si o, o da bi igbati enikan ba ti agadagodo, ti enikan dé bé ti o fi Kokoro si, gegebe ni ogun yi rio, o di eniti ba lo won

1. Ewe ogangan tabi pale, eke ti won fi ro ile, ao ha abala mejeji tio fi mu iganna, a wa fi abere tuntun merindiniogun (16) tele inu isasun tuntun, ao yo igbin ni tutu ao fi sinu isasun yi, oporo ekan lopolopo, ase Iru oka, ao lo yio kunna awa fise igbin yi ni odidi, nigbati obe yi ba tutu, ao mu abere ni owo otun ati ni owo osi, a wafi gun igbin yi awa ma Jaje, titi tia fi je igbin yi tan, gbogbo abere merindinlogun yi ni ao lo tan po. A wa mu eyo atare meta a fi si oju olo, ati ase iru oka kan, a o lo yi o kunna, abere tia fi je igbin yi ni okunrin na yio mu ti-yio fi sin gbere meta ni ehin re, yio wa fi ogun ti alo si oju olo yi si,a wa ko awon abere yi pamo, a ko ni lo abere na mo o.

2. Oboro igi iya, ao lo ro irin oboro meta kekeke, ewe-ogangan, egbo aringo, egbo osunsun, a wa ja ewe osunsun ati ewe aringo. A wa lo gbogbo ewe yi po mo igi oboro iya, a wa fi se igbin je, oboro irin ti a ro nia fi tele isasun, iyere si ni ata re.

3. Oko oruko, oko pepeiye, ewe ela, ewe ale, ao lo yio kunna, afi owu bo abere ni idi a fi gun igbin loju, ao lo ase iru oka si, a wa fi se igbin ati konko ati akere pelu, nigbati-obe yi ba jinna, a wipe abere ki fi okuu st idi nu, akere ki be ko ma to, bi igbin ba fa ikarahun atele, a o je obe na.

4. Ele aja, ele oruko, ao yi eni pakiti-pada, ao re diedie ni ibi igun re mererin, a wa lo gbogbo re yio kunna dada, lori eni pataki ti a yi pada yi ni okunrin na yio ti joko, la wa ba fi sin gbere yi gbogbo idi re po, were ni yio si ba obinrin na sun

5. Ao lo eésan ekuro, egbo pale, egbo ajade, ewe ina funfun, A o lọ, a wa po pọ, okunrin ati obinrin ni yio fi ose yi taba, were ni yio si basun.