OGUN LAKUEGBE

1. Epo ahun, egbo akogun, egbo seyo, ata, orogbo 9, Atare 9, a o gun gbogbo re po, ao ma fi mu oko gbigbona

2. Egbo agbasa, egbo ifon, ego tude, epo ogano, epo buere, epo jebo, alubosa elewe, ao se ni agbo, oluware yio ma mu, yio si ma fi we.

3. Egbo ogiri isako, egbo aparun, eresile ewe ahun,a o se ni agbo, ao ma mu, ao si ma fi we.