OGUN ERO MAGUN

OGUN ERO MAGUN


1. Ifun ako aja ti o ba se dede ikadi eni, ewe bomubomu ao lo, eku eliri, odidi atare kan, odidi eiyele kan, ati ifun ati gbogbo ohun ti ba mbe lara re, a wa gun gbogbo re po, ati ewe mafowokanomomi,

A ma bu diedie sinu asofu tio ba ka idi eni, a wa ran ni onde sidi, bi a ba fe ba obinrin sun a fi onde yi bo idi, bi a ba sise tan, a o bo onde na pamon, Ogun enia ama le se onde lara gbogbo ohun tia gun-yio, ifun aja tia fi won idi yi, a ko ni gun mo ohun ti a gun, inu aso funfun ti a ran ni onde ni a fi si ti won o ba ni ran mo, onikaluku ni yio fi ifun aja won idi tire o.

2. Eku eliri, ti ko ba bo ni ibi kankan, awa fi atare kan sinu omi, nigbati o ba ro, a wa la a o yo gbogbo omo inu re kuro, a wa ki eku eliri yi sinu epo atare na, awa koni ikobere, ama fi bodi bi aba fe ba obinrin sun, bi a basi tise tan ni ao bo pamo

3. Egbo bomubomu ati ewe re, a wa pepé, egho orombo lakuegbe, egbo opggki, a wa gun gbogho re bi agunmu, a wa rg sinu igo bi mefa, oti ni a O tusi gbogbo re patapata, a wa so gbogbo igo yi MQ ojy ina, eniti o ba ko mogun ni yio ma mu.

4. Egbo sigo, egbo legunsoko, ao pa pepe pelu omi oja ikoko, ati omi ogede odo, a wa ro awon omi gbogbo nkan wonyi sinu igo, a wa tu oti ebo da si, eniti o ko mogun yi yio ma mu ni tobila kankan ni araro

5. Egbo kojumodiro, ekolo lọpọlọpọ, aja okunrin, ao ma yo ido idi re sinu igo, epo aye, aopa pepe, ito malu, oti ebo, a o ro sinu igo, eniti o ko mogun yi yio ma mu ni igba meta ni ojojumo, ogun na dara pupo fun imu ẹni bẹ

6. Ogidi emu, egbo sẹyo, egbo-tude, ito obirin , epo-ira, omi oja-ikoko, a wa pa gbogbo re po, a wa ro sinu igo, a si fi obuotoyo si, eniti o ko mogun yi yfo ma mu.

7. Eje Ire lopolopo, ikakue, adigbonnaku, a o gun gbogbo re po pelu ekolo ologi lopolopo, omi orombo were, pelu oti ebo ni omi re, eniti o ko mogun na yio ma lo.

8. Ẹlẹjẹ: Omi esin tutu, apola oka, a gun awon mejeji yi po, a o po po mo ose, eniti o ko mogun yi yio ma fi we

9. ELEJE: Ejo paramole kan, esan kan, odidi-atare kan ao jo ao fi sin gbere yi-idi po.

10. Odidi oka kan: apola ako aja, ifun akukọ ati iwere, ao jo gbogbo re pọ, lati ori ọmọde ati agbalagba ko ko enikan, a fi obirin ni ki sin nibe, idi na nia fi. sin yipo asima tola, sugbon ase tele ni eleyi o.