Ogun atosi

OGUN ATOSI

1. Egbo asunwon ati ewe re, egbo atori ati ewe re, tangiri, isu aidan, isu erin, ogede agbagba pipon, ata, Alubosa, iyọ, orogbo 6, atare 6, ao gun gbogbo re po, a má fi mu ek gbigbona

2. Ewe boni, alubosa elewe, ogede wẹrẹ ati iyo, a o gun gbogho re pọ, a ma fi mu eko gbigbona.

3 Ewe itakun okẹrẹ, egusi, ao se ni ọbẹ ni, ao je fun atosi. .

4. Omunu-asunwon, a fi pẹpẹ rẹ, iru, alubosa ao se ni obẹ

5. Ao sun bara ninu ina, kanhun bilala, ao fun omi bara yi awalo kanhun si, yio ma mu. Ma fi oju di won bi won ti kereto yi o

6. Epo iyere, bara, eru-awonka, ao la bara yi sinu oru, a sika epo Igi iyeye na sinu oru, ao fi kan-hun si ko gbodo ru pana yio mu ni owuro ọjọ keji.

7. Ina-asunwon ebo, ao sa lorun yio, gbe kanhun bilala, ao se oluware yio ma mu.

8. Egbo ogbolo, ao pa pepe, ao ko sinu sago, bara ti o ba tobi, epa ikun, ao wa gun gbogbo re po, a wa kosinu sago, ogidi, emu, oluware yio ma mu.

9 Ao gbo ewe obi gidi, a ma mu, e ma fi oju di bio ti mo yi o, Ogun gidi nio.

10. Ogomo Opẹ ati ewe atori, ao gbo mejeji po oluware yi o ma mu.

11 Imi adie, ti inu ago ni, epo egusi, ao jo a wa lo imi orun mo, a wa ma kan adi si, a ma fi mu eko gbigbona.

12. Ọse, odidi adie dudu, Epo igi lafulẹ, iyo galo ganbari ni nta o, ati igi lafule na, epo igi afidihe, ewe patanmo, oju-oro, ọpọlọpọ irẹ, ao gun mo adie na, ao po ose mọ, yio ma fi we.