Aje ogun

AJE OGUN

1. Ao ke owo oga mejeji, Eyo atare Aja meji, ao lo, ao si fi sin gbẹrẹ yi orun ọwọ ka.

2 Atẹlẹwọ Iro, Odidi oga aye kan, Ẹyọ egusi Ito ogorun (100), Ewe oniyenye, ao jo gbogbo re po ao fi sin gbẹrẹ si ọrun ọwọ mejeji

3. Igbawọ Elegbede tabi owo Elegbede, owo Ologinni mejeji, emo Ajao mefa (6), eye arọ kan, ao jo gbogbo rẹ po, ao si fi sin gbẹrẹsi ọrun ọwọ ni o