OGUN BIBI OYUN IJU

OGUN BIBI OYUN IJU

1. Ọwọ ẹyọ Gbaguda kan, Ori alakedun, eso afọn, ekuro ayorunbo, ekuro ti ẹta su, ao jo, ito idi obirin na ni a ma fifo eko fun

2. Eyin adie mẹwa, obo esin tio ba bimo ri, obo ewure ti o bi mo ri, obo-agutan ti o bi mo ri, ao jo, ao di sinu aba owu, adi ni owu dudu, owu funfun, ao fi sinu ikoko, epo afon, odidi abọn eyin ẹyin, a wa ko gbogbo nkan wọnyi sinu apẹ, bẹ ni oluwarẹ yi o bi

3. Itoro ti o ba bo sile funra re lori iya re, eso pandoro ti o ba ja bo sile funra re, koko ori asewele, a o but nibi Igi panada, eru awonka kan, a o fi tele, a o se ni agbo, oluwarẹ yi o maa mu

4. Akara Ọgan, a o lọ, odidi atare kan, ẹkọ tutù ni a ma fi fọ mu