OGUN Bi OYUN BA NBU
OGUN BI OYUN BA NBU Ogun dada ni ogun na je, bi oyun ba mbu, bi a ba lo ogun yi, ni agbara Olorun, Oyun […]
OGUN BI OYUN BA NBU Ogun dada ni ogun na je, bi oyun ba mbu, bi a ba lo ogun yi, ni agbara Olorun, Oyun […]
ASOGBO Ohun ti a pe ni Asogbo ni wipe ki oyun ki o ba jẹ lara obinrin ni osu meta tabi mefa, tabi meje, tabi […]
OGUN OSE IWEBI 1. Ogun yi dara pupo fun eniti oba loyun, titi ti aboyun yio fi bimo ko ni si iyolenu fun obirin naa […]
OGUN ABIKU 1. Iyẹ adiẹ dudu, ewe abirikolo, eku asin kan, ọga kan, ẹgusi ti wọn ba ṣẹ silẹ ni ilẹ ọja ati ireke ti […]
SEJEBI:Arun yi nigbati obinrin ba bimo tan eje yio po, ohun ti si nfa ni awon agbalagba, ati ki oyi o ma ko eniti o […]
OGUN ORU INU Oru inu je arun tio buru ju ni ara obinrin, asima ba nkan je pelu lara obinrin, awa enia dudu aki pe […]
OGUN LATANLATAN Lataniatan je arun ti o buruju ninu gbogbo arun fun Obirin ki je ki obirin oni oyun, nigbakankan. Bi aba si se ogun […]
OGUN EKO Ogun ki ero le bo, bi obinrin, ba bimo tan ti o ku okan yoku, tiko bo, eleyi ni anpe ni ero, tia […]
OGUN IDADURO Bi obirin ba se alejo pari anlo ogun yi, bi obirin ko ba si ri alejo re loni, titi di ojo keta, a […]
Copyright © 2024 | WordPress Theme by MH Themes
Click one of our contacts below to chat on WhatsApp