OGUN ONKEPE

OKEPE je ogun ti ma dabo bo awa eda, bi a ba ni iroju ati se ogun yi. kosi ohun tio le ran oluware iba se afose, epe, tabi aransi, ogun yi yio ma daba bo wa bia ba le seo, ohun tia sise na ni wonyi.

1. Obi ajopa kan, ewe-asewele, eru awonka kan, ao jo gkogbo re po,ama fi sin eniti oba fe ni gbere mokanlelogun (21) lori.

2. Onkepe inu ewure, ewe-asewele, ao bu die nibe, igi panada, ao jo pelu odidi atare kan, a wa fi te ifa ogbe wehin.

Ofo: Oba sa ni seru aje, epedododo le pe aloran, ohun lo ba alubosa, o ba sa je ni epe fi ta si asorin lara, lasorin fike wonu igbo, eru ti osa di fun abuke, abuke ohun osa na ni di lo orun, ehin ti abiamo fi pon onic wole na ni fi pon bode, a wa ma fifo eko tutu mu. .

3. A gbẹ pẹpẹ abẹ oro igba (200), igba ido (200), igba lowerenjeje (200), a wa se obi ifin si igba (200), ati obi ipa si igba (200), a wa jo gbogbo re po, a wa ma fifo eko tutu mu.