OGUN LAKUEGBE 1. Epo ahun, egbo akogun, egbo seyo, ata, orogbo 9, Atare 9, a o gun gbogbo re po, ao ma fi mu oko […]
Month: January 2024
OGUN LOBUTU
1 Egbo ako ibepe, ewe re ati epo re, egbo ahun, ewe re ati epo re, egbo afoforo, ewe re ati epo re, eru awonka […]
OGUN LATANLATAN
OGUN LATANLATAN Lataniatan je arun ti o buruju ninu gbogbo arun fun Obirin ki je ki obirin oni oyun, nigbakankan. Bi aba si se ogun […]
OGUN JEWOJEWO
OGUN JEWOJEWO Ogun yi dara fun omode, ti jewojewo ba nje omode ki je ki osun, ki isi je ki omo o sanra, arun yi […]
OGUN JEYINJEYIN
OGUN JEYINJEYIN Arun yi a ma ba omode lenu jẹ, a ma damu agba na, sugbon ama ba omode ja pupo, a sima ba mode […]
OGUN JEDIJEDI
OGUN JEDIJEDI Arun yi ki je ki omode ati agbalagba ori igbonse se, ama rin enia nidi ti o ba nse obirin ko ni je […]
OGUN GBEYINRIN (tonic clonic seizure)
OGUN GBEYINRIN Arun yia ma mu ehin le toto, a ma mu ehin wa po. Eyi ki ise giri o, osi le ju giri lo. […]
OGUN GBOFUNGBOFUN
OGUN GBOFUNGBOFUN Gbofungbofun je arun ti ole tete pa enia, nitori ki je ki enia o le jeun, ama mu ahon dudu, omiran asi ma […]