OGUN JEYINJEYIN

OGUN JEYINJEYIN

Arun yi a ma ba omode lenu jẹ, a ma damu agba na, sugbon ama ba omode ja pupo, a sima ba mode lenu je.

1. Egbo Ẹlu, a o sun ni ina, nigbati a ba sun tan, ao lo yi o kunna, ao lo kanhun die si ati alomu ati iyere, a wa ma fi yi enu kiri, nigbogbo ese ehin ni a fira.

2. Alomu die, owo eyo kan, iyere a o lo yio kunna dada, ao kan ogi die si, a ma fi gbo eyin naa

3. Eso esin ao gun pelu iyere, a ma fi yo eyin na.

4. Eso gboyingboyin, ao lọ, alomu diẹ, Iyere, a ma fi gbo eyin na.