OGUN ETE

OGUN ETE

O je nkan ti oburu ju, osi le yo enia kuro larin ilu. Ero re ni yio.

1. Aso waji dudu, etu ibon, epo obo, ata pupa, imi ojo dudu, ao lo gbogbo re po, ao po mo ose, a o wa ko ose na sinu ikarahun igbin, awa ko oje oro-adete Si, yio ma fi we, yio si ma to si oju re.

2. Egbo toto, egbo orin-ayin, egbo sajere lopolopo, egbo-idi, egbo ewuro, ẹla eru, agolo etu ibon meji, omi iru, oti sekete, opolopo ata pupa, ao wa se, omi iru ni a fise omi re, yi o ma mu, yio si ma fi we.

3. Odidi ehoro kan, odidi atare kan, ao jo, ao da si adi-eyan, yio si ma la, yio si tun ma fi we.

4. Koropo wẹrẹ, ẹpa tutu, kahun bilala a o gun po, ose ni, yio ma fi we.