BI OBIRIN BA NSE ALEJO LORI OYUN

BI OBIRIN BA NSE ALEJO LORI OYUN

1 Ewe abirikolo, waji kijipa, ao bu omi sinu igba, ao gbo po mo ewe abirikolo, a wa ro sinu igo, obinrin na yio ma mu.

2 Igbin kan, Ogede wẹẹrẹ dudu kan, a o jo gbogbo re pọ, obinrin na yio fi ma fọ ẹkọ tutu mu.

3 Egbo ata ati ewe ẹru, ao fi awọ sinu ina, nigbati o ba jona, a lo po mo, a wa din pelu epo, iyo, obinrin na yio wa je.

4 Irun ori ti won fi ha si palapala ogiri, apadi ti o ba da oju de ogiri, irukere agbado, irẹ meta, odidi atare kan, ao lo gbogbo re po, obinrin na yio ma fifo ẹkọ tutu mu ni ararọ.