OGUN ORUN DIDUN.

Orun didun ki fun Eniti o ba ndun ni alafia, eniti orun ba ndun ko ni ni anfani ati le ru eru, beni ko ni le fe si oju wo ehin kio se se.

Ohun ti a silelo fun orun didun naa niwonyi

1. Egun orun aja, ao lo yio kunna, a wa fi omi Igbin ati ori si, ama fi pa orun na nigbakugba.

2. Rọrọ ọdan ao lo, pelu ori awa ma fi pa orun na nigbagbogbo.

3. Egbo-ogede, ti nse tinrintin, ao lo pelu oko atare kan awa fi sin gbere yi orun na ka.

4. Roro Saba, ao ja ao lo pelu oko atare,kan a fi -sin gbere yi grun na ka.

5. Ao ta eni atin ni -koko ni ona meji, ao so mo orun, eleyi ni anpe ni gborun dun.