OGUN NAGO

1. Ewe taba tutu, a o lo ewe yi, adi, a wa po po, ao ma fi pa abe

2. Eso-boni, ao lo ewe taba tutu tabi gbigbe mo, adi die, ao wa ma fi pa abe.

3. Ose, ewe taba, ao lo po ti yio kuna dada eni na yio wa ma fi taba.

4. Imi orun kanfo, ewe taba, ao lo gbogbo re po, adi agbon ni.a fi se epo re; a wa ma fi pa abe, o si dara fun ina ori papa.

5. Imi orun, kanfo, egbo ogbo, ao lo awon nkan meteta yi po, ada sinu adi, a wa ma fi pa, o si dara fun ina ori pelu.