Oogun Awoka Ara/Joint pain

Oogun Awoka Ara/Joint pain

Oogun Awoka Ara/Joint Pain

Oogun yii wa fun bi orikerike ara (Joints) ba n ro eniyan eyi ti won n pe ni Awoka ni Yoruba, oogun yii tun wulo fun arugbo ti orunkun ba n ro.  Bayi ni a se n se oogun awoka ara/joint pain

Ewe Ijan, Odidi atare kan (1), a  joo po mo ara won a o lo kun na, a o maa fi akara Kengbe jee, Otan