Agbo Iba Jefun Jefun (Typhoid Fever)

Agbo Iba Jefun Jefun (Typhoid Fever)

Agbo Iba Jefun Jefun (Typhoid Fever)

Iba Jefun Jefun naa ni opolopo mon si Iba Taifoodu, ti Oyin bo re n je Typhoid Fever. Eyi ni oogun ti o je Agbo fun Iba Jefun Jefun (Typhoid Fever)

Eepo Mongoro (Mango), Eepo Oganho, Ewe Laali, Orombo weere (a o laa si), a o bu omi gidi si, a o see lori ina yi o jin na, a o maa mu ni igba kuu gba, (150CL, 4x a day). otan