Ogun Aleko (Agunmu)
Egbo Ifon, Ifofo Okun, Baaka, Orogbo (20), Alubosa Elewe, Ata dudu die, iyo, a o gun po, a o sa yi o gbe, a o […]
Egbo Ifon, Ifofo Okun, Baaka, Orogbo (20), Alubosa Elewe, Ata dudu die, iyo, a o gun po, a o sa yi o gbe, a o […]
Ogun gbanu gbaha, Eniti arun yi ba nse, inu re yio wu lati aiya de odo abe, o si le wipe oso ohun ni egbe, […]
OGUN BI OYUN BA NBU Ogun dada ni ogun na je, bi oyun ba mbu, bi a ba lo ogun yi, ni agbara Olorun, Oyun […]
ASOGBO Ohun ti a pe ni Asogbo ni wipe ki oyun ki o ba jẹ lara obinrin ni osu meta tabi mefa, tabi meje, tabi […]
OGUN OSE IWEBI 1. Ogun yi dara pupo fun eniti oba loyun, titi ti aboyun yio fi bimo ko ni si iyolenu fun obirin naa […]
OGUN ABIKU 1. Iyẹ adiẹ dudu, ewe abirikolo, eku asin kan, ọga kan, ẹgusi ti wọn ba ṣẹ silẹ ni ilẹ ọja ati ireke ti […]
WERE: je arun tio po ju ni ile awa enia dudu, ahun ti nsi ma fa were ni awon nkan die ti ndaruko wonyi: Mímú […]
TUNTUNYUNYUN je arun tio buru ju fun eni gbogbo, a si ma yara mu gbogbo omo ika ese tia fi nse anfani kuro nibé, ibere […]
Copyright © 2024 | WordPress Theme by MH Themes
Click one of our contacts below to chat on WhatsApp