Bi a se lè mú oko Tobi ni ailo oogun kankan

Spread the love

Bi a se lè mú oko Tobi ni ailo oogun kankan

Orisirisi nkan ni o ma n fa ki oko o kere tabi ki o sun ki, a lè pin oko kekere sí ònà meji

1. Awọn oko ti wọn kéré lati igbati ti a ti bi wọn

2. Awọn oko ti o je wipe wọ́n tobi ni iwonba tabi tobi dáadáa tẹlẹ ṣugbọn awọn ohun kan ni o fa ti oko naa fi kéré sí tàbí o sun ki.

Awọn oko ti wọn kéré lati igbati ti a ti bi wọn, bawo ni a ṣe lè mú tobi ni ailo oogun

Fún àwọn ti oko won ba kéré lati igba ti a ti bi wọn, ki wọn o máa fi owo fa oko wọn ní àárọ̀ ní àárọ̀, eyi  dara ju ti a ba n se ni gbogbo ogun iseju (20 minutes), a o si máa ṣe eyi ni igbati oko naa ba le. Ẹni tí oko rẹ kò bá lé dáadáa kí o ra Agbo Cobra bitters, eyi o mú oko naa le ti yio sì ṣeé fi owo fa dáadáa, bawo ni a ṣe n fi owo fa oko?

A o gbe ọwọ sí ibi tí oko ti bẹrẹ, a o nii ko ẹpon mọn o. A o fun owó mon diẹ, a o waa fi ọwọ wọ oko naa lati ibi ti o ti bẹrẹ wa si ibi ori oko náà, a o yọ ọwọ kuro a o da pada Si isalẹ oko, a o tun fi ọwọ wọ wá sí orí oko naa, a o se eleyi lera lera, a o si máa ṣe ni ogun iseju (20 minutes) sí ara wọn, ẹni tí ko ba le se ni ogun iṣẹju sí ara wọn ki o máa ṣe ní àárọ̀ ní àárọ̀.

Fún ìbéèrè miran lori eyi ti a mu enu ba yii, è bami sọrọ ni ibiyi tabi ki ẹ tẹ àmì WhatsApp ti o wa ni ojú screen yin

Kini o ma n fa ki oko ti o ti tobi tẹlẹ o maa kéré sí tabi sunki

Nkan meje ni o ma n fa ki oko kere tabi sunki, awọn nkan meje nooni iwọnyi

1. Ọjọ Orí

Ojo ori, agba ti de
Ojo ori see maa je ki oko omokunrin o kere


Ti eniyan ba ti n di agba, a máa fa ki oko eniyan o máa sunki tabi kí o máa kere sí, eyi ma n ṣẹlẹ nipasẹ wipe irorun ti dé, kò sí iṣẹ ti o le kankan mọn bẹẹni ọpọlọpọ kii se ere idaraya mon, fifi ara ẹni ṣe iṣẹ tabi se ere idaraya a máa jẹ kí ẹjẹ kí o lọ káàkiri gbogbo ara dáadáa, sugbon ti agba ba ti n dé, ọpọlọpọ o ki n se awọn nkan yii mọn, èyí a máa fa ki òróró ati ọrá o máa wà nínú ẹjẹ ẹni a sì tún máa jẹ kí ẹjẹ kí o ma se sinmi sí inú oko tó bẹẹ, èyí a sì máa fa ki oko o sunki.


2. Sisan ara

Effect of weight gain on Penis
Effect of weight gain on Penis

Gẹgẹ bi alaye ti mo ti ṣe ni òkè yìí, ki òróró ati ọrá o máa wà nínú ẹjẹ ẹni a máa fa ki oko eni o máa sunki, èyí a máa ṣẹlẹ sí ẹni ti o ba sanra ti ọrá sí pọ ni ara rẹ

Ohun miran ni wipe, fún àwọn tí o bá sanra, awọn ẹran ati ọ̀rá ti ó wà ní ibaradi wọn a máa fa oko wọn sínú tí oko naa ko sí níí jáde dáadáa

3. Isẹ abẹ agbẹ̀dù abẹ́ (Prostate surgery)

effect of prostate surgery on penis size
effect of prostate surgery on penis size

Iwadi fi múlẹ wípé àwon ènìyàn ti wọn ṣe iṣẹ abẹ fún nitori ìsoro agbẹdu abẹ (Prostate problems, be it enlargement or any other) tàbí jẹjẹrẹ agbẹdu abẹ (Prostate cancer) le rí ìyípadà nínú gígùn ati inipọn oko wọn, eleyi a máa sáábà pada sípò fúnra ara rẹ, ṣugbọn ti ko ba pada bọ sípò, e le bami sọrọ ni ibiyi

4. Àrùn lọ́kolọ́kó (Peyronie’s disease):

Àrùn lọ́kolọ́kó ni o ma n fa ki oko eniyan o lọ, a máa tẹ oko ti yi o ri kọrọwọ, a sì máa fa ki oko o máa ro ẹni ni igba tí oko ba lé.

Àrùn oko lílọ́ yìí a máa sáábà se àwọn ènìyàn ti ọjọ ori wọn wà ní àárín ogoji odun sí àádọ́rin ọdún, àrùn oko lilọ yii n wọpọ sí débi wípé àwon ọkunrin ti ọjọ ori wọn wà ní bíi ọgbọn ọdun náà ti n ni

 

5 Oogun lilo

bi awon OOgun oyinbo ti won n lo si arun agbedu abe see maa fa oko kikere
OOgun oyinbo

Orísirísi oogun ni a n lo, paapa julọ oogun oyinbo, awọn oogun kan wà ti o ma n fa ki oko eniyan o máa sunki tabi kéré sí, awọn ti a n lo fún àwọn tí wọn ba n ronú ju tabi awọn tí ọkàn wọn o ki n papọ a máa fa ki oko o sunki tabi kéré, oogun ti awọn ti won ni àìsàn agbẹdu abẹ ma n lo naa a máa fa ki oko o kéré

6. Siga ati Ọti mímu

Awọn eroja ti o wa ninu ọti ati siga a máa ba iṣan ara jẹ, èyí a sì máa ṣe idiwọ fún ẹjẹ lati wọ inú oko dáadáa, leyi ti o já sí pé, ọko ko níí lè dáadáa.

Akiyesi Pataki: Gbogbo okò tí kò bá lé dáadáa yi o máa sunki ni, yi o si máa kéré, e di èyí mọnwo

Bi Ase lè mú oko kekere Tobi, tabi ki oko ti o sunki ki o Gun si pada.

1. Ki awọn eniyan ti o ba ti n to Ogoji Ọdun (40 years old) o máa ṣe ere idaraya

Àwọn tí wọn ba ti to Ogoji odun tabi ju bẹẹ lọ, ki wọn o máa rìn kaa kiri, ki wọn o máa ṣe awọn nkan ti yi o máa gbé ara wọn tabi eya ara wọn kuro ni ojú kan náà

2. Ẹni tí o bá sanra, ki wọn o máa ṣe ohun ti yi o mú wọn tẹẹrẹ.

 Ìdí eleyi ni wipe gẹgẹ bí mo ti sọ ni òkè wípé àwon tí wón sanra, oko wọn kìí jade dáadáa, ọ̀rá ti o wa ni abẹ́ ikun won yi o máa fa oko wọn sínú, nitori náà, ki wọn o máa ṣe ere idaraya tabi ki wọn o máa ṣe ohun ti yi o mú wọn tẹẹrẹ. Ogun ibilẹ fún àwọn tí o sanra, ti wọn fẹ tẹẹrẹ wa, ẹ kan sí mi ni ibiyi lati ra

3. Ki a máa fi ọwọ fa oko

Ki ari wipe a o ni idakole tabi ìṣòro kankan nípa oko líle, ki a sì máa fi owo fa oko ni gbogbo igba, eyi yí o maa mu iṣan ti o wa ninu oko wa na, ẹjẹ yi o máa sími sibe, awọn iṣan yi o máa ran, wọn o sì máa tobi Si, oko yi o máa tobi Si lati ipasẹ bẹẹ. Eleyi ko le seese fún àwọn tí wọn ba ni idakolẹ tabi oko wọn ko lè dáadáa, ìsoro oko ti o le ni ki wọn o kọkọ mu oju to ki wọn o too máa wa bi oko yi o se tobi, ẹ le rí oogun idakolẹ tabi oko ti ko le ra nibi

4. Awọn tí won ba ni ailera pẹlu agbẹdu abẹ (Prostate problems)

Isẹ abẹ agbẹ̀dù abẹ (prostate surgery) a máa fa ki oko o máa kéré, sugbon fún ìgbà díẹ nooni, ki eni bẹẹ o se sùúrù, oko naa yi o si pada bọ sí ípò

5. Oogun lílò

Awọn oogun (oogun oyinbo) kan a máa fa ki oko omokunrin o máa sunki tabi kéré sí, eleyi wọpọ laarin awọn oogun ti won máa n lo sí àwọn isoro agbedu abẹ ti o ba tobi ju Bi ọsẹ yẹ lọ (enlarged prostate), nitori náà, ki eni ti iru eleyi ba n se ki o béèrè lọwọ àwọn dokita ohun ti o le se tabi ki o bẹrẹ sí níí máa lo ogun ibilẹ sí ìsoro agbedu abẹ rẹ

6. Iwosan Àrùn lọkolọko (Peyronie’s disease

Àrùn tí o ma n lọ enia ni okó yìí, ona ti a le gbà Dẹkun re ni ohun elo kan ti awọn oloyinbo n pe ni Penile traction device, a lè fi eleyi na oko náà ti yi o si tọ́ọ́ bi o ti yẹ

7. Ọti ati siga mímu

Awọn eroja ọti ati siga mímu a máa fa orisirisi ailera Ibalopọ fún okunrin eyi tí oko kikere jẹ ọkan lára wọn. Awon eefin siga yii a maa parapo mon eje a si maa di awon isan ara ti eje n gba koja lo si inu oko

Eni ti o ba ma n mu oti tabi siga ki o da duro, ki o si lo ohun ifonu (detoxifier) lati fo awon idoti inu naa danu. ki eni naa o maa se ere idaraya daadaa, oko re yi o si pada bo sipo. iru awon eni ti won ba n mu siga a maa ni isoro ati mu oko won le, awon yii naa le ra Cobra bitters lati mu oko won maa le, isoro oko kikere yi o si d ohun igbagbe 

Fun ibeere miran tabi iranlowo kankan, e kan simi ni ibiyi 

2 Comments

  1. Pls whenever am with a woman my penis we not stand sometime if am alone is stand and also i av a sma penis issue am a man of 33 years old pls help

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*