
Ogun tapa Yodi
Ewé Igi òrúru, Akogun, Àlùbósà Elewe, A ọ lọ gbogbo rẹ pò, a ọ máa fi muko gbigbona otàn
Ona omiran ti a tun le gba see ni yii (Part 2)
Ẹrẹlẹ ewe ipin, padi atare kan, a ọ jọ pọ, a o po mọn ori, a ọ ma fi pa ẹnu furo eni naa otàn
E le kan si mi ni ibiyi lati ra ogun jedi jedi, idi yiyo ati tapa , bakan naa fun eyikeyi ibeere yin
Leave a Reply