
Ọsẹ kòkòrò tí o daju
Orisirisi Arun awo ara ni o wa ni aye ode oni gege bii rorẹ́, lapalapa, tan mọn na, omo ika owo ti o dudu (dark knuckles), bàtábàtá ara (stretch marks) ati beebeelo
Ọsẹ kòkòrò tí o daju ti ẹnikẹni le ri ni Ile nigeria ni Zeezah soap ti an lo fún gbogbo arun awo ara eyi ti o wù kí o jẹ
O n sise fun lapa lapa ara, ara ṣiṣu, rorẹ́, eela, ati gbogbo kòkòrò ara patapata, egberun mesan (#9000) ni a n ta
Bakan naa ni a fi eha ara ọfẹ kan sii (free body scrub) fun gbogbo ẹni ba féé ra ọsẹ kòkòrò náà, eha ara yìí(body scrub) yoo ha gbogbo idoti ti o wa ni awo ara danu ti yi o sì mú gbogbo ara jolo si
₦9000 ni a ta mejeeji, e send message si wa nibiyi lati raa nibi



Leave a Reply