Agbo Oko omokunrin to Kere

Spread the love

Agbo Oko Omokunrin to Kere

Orisirisi ona ni a n gbaa se itoju oko omokunrin ti o kere ti yoo fi gun ti yoo si tobi si. Iru Ona ti a o gba toju Oko naa da lori ohun ti o ba fa kikere ti oko naa kere.

Orisirisi nkan ni o ma n fa ti oko omokunrin fii maa kere loju ara sugbon ohun meje pataki ni o ma n fa, ninu eniyan mewa ti oko won ba kere, mesan ninu won ni isoro yii nitori eyokan ninu awon idi yii ni, awon okunfa naa niyi

Okunfa ki Oko omokunrin kere

1. Ojo ori
2. Ki eniyan o sanra
3. Ise abe Agbedu abe (Prostate surgery)
4. Arun roko roko (Peyronie’s disease)
5. Oogun Oyinbo
6. Oti, Siga tabi igbo mimu
7. Adamo oko kikere

Bawo ni a se n je ki oko omokunrin o gun si ti yoo si tobi si

Eyikeyi eyi ti oba je ninu awon okunfa ti a ti ka soke yii, ohun kan naa ni o ba gbogbo won wi ti yoo si je ki oko omokunrin ti o kere tabi eyi ti o tobi tele ti o wa sun ki ki o tobi si ki o si pada si ipo to ye ki won o wa.

1. E ra Agbo Oko ti o kere 

Premature ejaculation cure and penis enlargement cure
Penis enlargement herb, Premature ejaculation cure and weak erection cure and treatment

E le te ibi lati ra Cobra bitters ti o je Agbo oko ti o kere lati mu tobi ti yi o gun si  tabi ki e lo ami whatsapp ti wa ni oju ero yin

2. E mu ilaji agbo naa, e mu ilaji yoku ni eyin wakati mejila

3. E maa fi owo fa oko naa ni laaro laaro ati ni aale ki e to sun fun ose meta

4. E maa se ere idaraya ni gbogbo aaro ni eyi ti yoo gba o kere ju ogun iseju (20 minutes):  eleyi se pataki fun awo ti won ba sanra nitori wipe ni opolopo igba awon ora ti o wa ni isale ikun ni o maa n bo awon isan kan ti o wa lara oko mole ti ko nii je ki ojo naa ki o jade daadaa, Agbo cobra bitters yi o si je ki eje ti o n san kiri ara ki o maa de inu oko naa daradara ti yi o si jade sita daadaa

Fun ibeere tabi ohun kohun ti o ba ru yin loju, e kan simi ni ibi yii

8 Comments

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*