Ojuda Agbo Lobutu/ Ese to wu (Swollen Leg)

AGBo lobutu for curing swollen leg
black man/ Nigerian's leg
Spread the love

Ojuda Agbo Lobutu/ Ese to wu (Swollen Leg)

Eleyi ni oogun ese wiwu

Odidi Isu gbegbe, isu ogi isako, Igi Ahun (ase ale, ase aaro ati ere sile ewe re), egbo oruwo ati ewe re, epo pandoro, ewe agbari etu, ewe oparun, enu opiri, oro agogo, Epo oganho, eru alamo, aidan, to ba se okunrin a o fi ori akuko adie tele agbo naa, to ba se obinrin a o fi ori abo adie ayebo tele agbo naa, omikan la o fise, yi o jina, yi o maamu, yi o maa we, yi o maa fi joo otan!

herbal cure to Swollen leg Lobutu

Ose Re

“ewe tamolabiya”, “eepo orogbo”, “oje botuje”, “eru awonka”, a o gun papo mose, a o ma fi we ese naa

2. Egbo ifon/itan, Egbo tude, Isigun, Iseta, Àlùbósà, Eléwé, Kahun bílálà,kana furu, kafura, a o Gun won po, a o rọ sinu igo kan, a ó da oti sí a o máa mú, bi oti yii ọ ba to tabi ki a fo omi òrombó diẹ Lu ki oti náà ma ba p’oju

3. Orógbó meta, Obi meta, atare meta, eru ibon, iyo àlùbósà eléwé ,ata dúdú,obi ajo pa meta,a o Gun papo a o máa fi eko gbigbona lo

4. Ewé Oparun, Ewé Mongoro, ati egbo re ati eeru sinu apẹ, enia yi ọ máa mu

You can contact me here for any health complain here as well or order any product by clicking the WhatsApp button on your screen

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*