Ogun tapa Yodi

Spread the love

Ewé Igi òrúru, Akogun, Àlùbósà Eléwé, a o lọ gbogbo rẹ pọ, a o máa fi muko gbigbona, otàn

2. Ẹrẹlẹ ewe ipin, padi atare kan, a ọ jo pọ, a ọ pọ mọ orí,a ọ máa fi bo furo omo naa

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*