Ogun Ale todaju

Spread the love

Ogun Ale Todaju

 

1. Ogun Ale Todaju

Okuta ako, Ori ahun, etu ibon, a o lopo, yi o ma fi foko tutu mu.

Ofore: Iyokuyo ni ahun n yori, igba ku gba letu ngba, ilekule ni ako okuta n le

2. Ogun Ale Todaju (Oni Eyin Ororo)

Ewe Awon Ekun, a o lo yi o kuna, a o po eyin ororo adie kan mon ati oyin igan, Okunrin naa yi o maa la

3. Ogun Ale Todaju (Oni Alangba Adaripon)

Ori alangba adaripon kan, ewe elu, a o gun mose, a o ko sinu aloku oko, nibe ni eni naa yoo ti maa bu ose yii for oko re

4. Ogun Ale Todaju (Oni Eja Abori)

Egbo ogbolo tutu, eja abori kan toto ni, opolopo suga, a o gun lodo, ehin igba tabi ehin ate la o sasi, a o ma sa lorun, to ba gbe, a o lo lubulubu, a o maa fi muko, gbigbona otan a o lo pelu kanhun bilala

5. Ogun Ale Todaju

Oko ese, owoja erin, eso omu oja, a o jo won po, a o da sinu Oyin, a o maa la

You can as well get Cobra bitters for Strong and long-lasting erection  

Contact me for any kind of health and spiritual solutions here 

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*