
Awure Asoro Ti Odaju
Oku Ofon ti won gbe sosita, ewe awerepepe, ewe iyawe, iru, ogiri, padi atare kan, Eja eda, ede funfun, a o jo won po, a o te ni ejiogbe
Ofore: Iru loni ki e ma wa towotowo, ogiri lo ni ki e maa da girigiri, ewe iyawe loni ki e ya wa si odo mi, eda loni ki e ma da wa, ki e maa da wa towotowo, tewe tagba nii bere iyo, tewe tagba nii ri ofon ni ita, oniwe ni wa ounje fun ofon, awerepepe pe okunrin wa, pe obinrin wa, a o da sinu akerengbe, a o da iyo egbefa si, a o so ro.
You can contact me here for any health and spiritual complain as well or order any product by clicking the WhatsApp button on your screen
Leave a Reply