Ifokomu kokoro eela

Spread the love

Ifokomu Kokoro Eela (Eczema)

Orombo Lakuegbe (Guin guin), ose dudu, aladi, enu opiri, a o jo, a o maa fi foko mu

Agbo kokoro eela

Eepo Oganho, epo oro, Egbo Ogbo, egbo osunsun pupa, egbo inabiri, oro agogo, oro adete, eru alamo, ata pupa (ata ijosi), ata ni ao fi tele o, a o se lagbo lori ina, a o maa mu , a o maa we

Ose Eela

Alubosa Onisu, Alubosa Gambari ti a n pe ni Ayu, baka, sinkinmini, a o gun po mose, a o maa fi we

Bakan naa e le ra ose kokoro to daju nibiyi

Tabi ki e bami soro fun isoro ilera eyi tabi omiran pelu ami whatsapp ti o wa ni oju ero yin yii

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*