
Agbo Iko
Ewe jagunrase, a o ko sinu oru, ogede were meta pipon, a o ko si, a o se lagbo, yi o jina yio mamu. Oogun yii sise fun Iko eni ti oni corona virus ti aba fi opolopo eeru alamo kun (kii se ogun covid-19) sugbon o le dekun iko re
You can contact me here for any health and spiritual complain here as well or order any product by calling +2347026264929 orĀ click there to send a message on whatsapp
Leave a Reply