Adodun

Spread the love

Adodun

Akekee (1), owoja erin, eweje mi ni o, a o gun papo mon oyin ati ori, a o ko sinu pokoto ti o n jo daradara, okunrin yi o maa fi pa oko ba obinrin sun

part 2 a

To ba se Okunrin ni yi o se ti yi o maa lo fun Obinrin,
Adaripon kan, a o yo oko re, a o pa akuko die, a o yo koro pon re mejeeji, ewe je mi ni o, ewe yesi, ewe amunimuye, a o gun won po, a o po mon Ori, a o ko sinu okoto tala to jo dara dara, a o maa fi wo oko ba obinrin sun.

part 2b
To ba se Obinrin ni a o se fun ti yi o ma fi gba nkan lowo okunrin, abo alangba la o yo obo re ati obo adie, a o fi nkan yoku kun bio ti isaju, ohun na otan

You can contact me here for any health and spiritual complain here as well or order any product by calling +2347026264929 orĀ click there to send a message on whatsapp

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*