
Ogun Iferan ti aa fii Fe Obinrin
Ewe Ogbo meta, Ewe alupaida, Oku Oga Kan, a o gun mo ose, a o fi omi ekun eleji po, a o kosi inu aso funfun, a o maa fi weju losi odo obinrin yii.
Ofore: Ogbo loni ki lagbaja gbo temi, apada loni ki o ma pa Ohun mi da, Aso alaso loga n gba bora, oro ti nba ba iwo lagbaja so ni ki o gbo, ekun elekun ni ekun eleji nsun
PS: Omi ekun eleji je omi kan ti o ma n jade ni ara igi lati ipase awon kokoro eleji ti o suru bo igi naa loke. Awon ode ni won saaba ma n ri
E le ri ogun iferan naa ra ni ibiyi ti e ba pe +2347026264929 tabi ki e te ibiyi lati bawa soro lori whatsapp
Leave a Reply