Aseje Awure (Wealth Booster)

Spread the love

Aseje Awure

Eku Ago kan, ewe amuni muye, a o se lobe, a o fi iyere osun tefa ese kan ola

Ofore:

Kiribiti ni mo ko ki n mi ikinmi, Kiribati ni mote iyee, ohun lose ese kan ola sere nile Ado, kunkun ni ki o mu ire mi o, mamu ire mi dengbere o, amunimuye emeso oko, kikun ni ki omure mi o, make mu ni dengbere, bi lakosin bakola sehin adenu omo re,.

Bi aba se obe yii tan, a o gbe kale, a o fi iyere osun te ifa re, to ba tutu, a o dasi, a o ropo, a o pa obi to ba dara fun, a o so pe; tori owo ni mose se iwo obe yii o,ki eda mi gba o, ki ire temi makoja mi o, a o ko si ori ifa yi, to ba di aaro, a o tun pe ofo yii si, a o koje nibe


You can contact me here for any health and spiritual complain as well or order any product by clicking the WhatsApp button on your screen

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*