
Aseje toko taya, fun Obinrin to nwa omo bibi
Egusi inu eso Iyalode funfun, iyere, iyo, epo, ekirieran nomo merin, a o lo egusi yen yooto sibi kan iyere re die, la o ba se, a o je to ba tutu tan….Otan
You can contact me here for any health and spiritual complain here as well or order any product by calling +2347026264929 orĀ click there to send a message on whatsapp
se oko ati iyawo ni yoo je aseje naa?
Beeni
Esheun baba sugbon ejowo eran melo ni okunrin maa je ninu e