
Agbo kuun (HERNIA)
Orogbo gbigbe yi o po, Atare to gbo ko to padi merin, a o yin omo inu re, egbo ewuro ijebu die, egbo ewuro jije die, eso akerejupon, yoo po bi orogbo, a o gun won po, a o ro sinu igo, a o ro oti le, yi o maa mu ni koobu kookan laraaro, pelu ogo olohun , yi o san
Part II
Imi Ojo die, a o lo kunna lubulubu, a o fi ajo joo, a o daa sinu adi ayan, a o maamu ni sibi kokan laro laro
part III Aseje re
Egbo teyo die, a o lo, aworoso die, a o lo awon mejeeji papo, opolopo iru wooro, ewe ewuro odo die, a o lo won po, a o ko sinu isaasun, a o fi epo ati iyo sii, a o jo eyin adie meta si, a o po po, a o se lobe je. idaji(early morning) laaje otan!
You can contact me here for any health complain here as well or order any product by clicking the WhatsApp button on your screen
Leave a Reply