
Oogun ki Okunrin le ri Aya ati ki Obinrin le ri oko
Part 1
Alangba sekelenje kan (1), Ewe ahun mefa a o gunpo mon ose, eni ti n wa aya yi o maa fi we
Part 2
Adie asa Oloro, a o pa, a o tu iye re, a ko gbodo je ki iye eyokan tadanu, a o ge adie yi lekiri lekiri, ewe loko lepon, a o fi se Adie yii lobe je peku epo, ata, iyo, ati Alubosa. Ao waa jo iye ati eegun re papo mose a o maa wee
click here to Contact me for spiritual help in finding a suitor, a man(husband) or woman (wife)
Leave a Reply