
Agbo Eje Riru (High Blood Pressure)
Omi osan weere, Omi osan Lakuegbe (ohun naani a mon n pe ni osan jaganyin), ewe omisinmisin itakun, Ewe dasa, ewe Oruwo, Ewe Pear, Afomo igi eyikeyi ti aba n je eso re, ko baa se afomo obi tabi orombo tabi osan agbalumo tabi orogbo, Ko saa ti je igi ti a n je eso re, a o ja a o fi alubosa gambari si, Ao see gbogbo re ni agbo lori ina ti yi o jina dara dara, eni naa yoo maa yo mu ni ife (cup 25cl) lojoojumo laro, losan ati lale pelu sibi oyin kan ninu cup kookan
You click here to order for Hypertension that help to regulate high blood pressureĀ
You have any questions to ask me? Whatsapp me with the button on your screen or click hereĀ
Leave a Reply